Ọrọ Orúkọ (Noun)

 Ọrọ Orúkọ (Noun)

Ọrọ Orúkọ ni awọn ọrọ tó lè dá dúró nipo oluwa, abọ ati ẹ̀yán.

i) Olùwà

Olùwà ni olùṣe inu gbólóhùn. 

Àpẹẹrẹ: Tade je eba

Femi ra ọkọ tuntun

Nínú àpẹẹrẹ òkè yìí, Tade ati Femi ni o je ọrọ Orúkọ nipo oluwa.

ii) Abọ: Abọ ni olufaragba ohun ti oluwa n se nínu gbólóhùn.

Àpẹẹrẹ:Tade je eba

Femi ra ọkọ tuntun 

Eba ati ọkọ ni abọ nínú àpẹẹrẹ yìí

iii) Ẹ̀yán: Èyán máa wáyé nígbà tí ọrọ Orúkọ meji ba tele ra won, ọrọ Orúkọ keji máa jẹ eyan.

Àpẹẹrẹ: Eja alaran-an ni mo ra

Baba Kemi wo bàtà tuntun


Ise Síse

Kọ gbólóhùn marun ki o si fala sí ọrọ Orúkọ inu rẹ

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

Alifabeeti Ede Yoruba (Yoruba Alphabet)

Faweeli Ede Yoruba