Nínú iro aarundinlogbon to wa ninu èdè Yorùbá mejidinlogun je konsonati. Awọn niwonyii: B,D,F,G,GB,H,J,K,L,M,N,P,R,S,Ṣ,T,W,Y. In Yoruba language there are 25 alphabets, which 18 of it is Consonants. Above are the Consonants sounds in the Yoruba alphabets.
Ninu Ede Yoruba Alifabeeti marundinlọgbọn lo wa (25). Mejidinlogun (18)ninu won je iro konsonanti ti meje yooku je iro faweli . Bayii ni a se n ko leta Ede Yoruba sile: A B D E Ẹ F G GB H I J K L M N O Ọ P R S Ṣ T U W Y. Awon iro faweli niwonyi: A E Ẹ I O Ọ U. Iro konsonanti niwonyi: B D F G GB H J K L M N P R S Ṣ T W Y. The Yoruba language alphabet is made up of twenty five letters( 25). There are eighteen consonants and seven vowels.
Faweeli ni awọn iro ti kìí sì idiwo fún èémí nigbati a bá n pe won. Faweeli méjìlá ní o wa nínú èdè Yorùbá. Awon niwonyii:A E Ẹ I O Ọ U AN EN ỌN IN UN. Méje je Faweli airanmupe: A E Ẹ I O Ọ U Marun-un je faweeli aranmupe:AN EN IN ỌN UN
Comments
Post a Comment