Faweeli Ede Yoruba

Faweeli ni awọn iro ti kìí sì idiwo fún èémí nigbati a bá n pe won. Faweeli méjìlá ní o wa nínú èdè Yorùbá.

Awon niwonyii:A E Ẹ I O Ọ U AN EN ỌN

IN UN.

Méje je Faweli airanmupe: A E Ẹ I O Ọ U

Marun-un je faweeli aranmupe:AN EN IN ỌN UN

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

Alifabeeti Ede Yoruba (Yoruba Alphabet)