Alifabeeti Ede Yoruba (Yoruba Alphabet)

Ninu Ede Yoruba Alifabeeti marundinlọgbọn lo wa (25). Mejidinlogun (18)ninu won je iro konsonanti ti meje yooku je iro faweli.
     Bayii ni a se n ko leta Ede Yoruba sile:
A B D E Ẹ F G GB H I J K L M N O Ọ P  R S Ṣ T U W Y.

Awon iro faweli niwonyi: A E Ẹ I O Ọ U.
Iro konsonanti niwonyi: B D F G GB H J K L M N P R S Ṣ T W Y.

The Yoruba language alphabet is made up of twenty five letters( 25). There are eighteen consonants and seven vowels.

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

Faweeli Ede Yoruba