Faweeli Ede Yoruba
Faweeli ni awọn iro ti kìí sì idiwo fún èémí nigbati a bá n pe won. Faweeli méjìlá ní o wa nínú èdè Yorùbá. Awon niwonyii:A E Ẹ I O Ọ U AN EN ỌN IN UN. Méje je Faweli airanmupe: A E Ẹ I O Ọ U Marun-un je faweeli aranmupe:AN EN IN ỌN UN